Adura Oluwa lyrics
Songs
2024-12-24 12:50:04
Adura Oluwa lyrics
Baba wa ti mbẹ li ọrun;
Ki a bọ̀wọ fun orukọ rẹ.
Ki ijọba rẹ de;
Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe,
bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye.
Fun wa li onjẹ õjọ wa loni.
Dari gbese wa jì wa,
bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa.
Má si fà wa sinu idẹwò,
ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi.
Nitori ijọba ni tirẹ,
ati agbara, ati ogo,
lailai.
Amin.
- Artist:The Lord's Prayer